Oyún ṣíṣẹ́ àti ọmọ bíbí ní ọjọ́ iwájú.

Ṣé òògùn ìṣẹ́yún lè fa àbùkù sí ọmọ tí mo bá bí lọ́jọ́ iwájú lára?

Rárá o, òògùn ìṣẹ́yún ò lè fà àbùkù sí ara ọmọ tí o bá lóyún rẹ lẹ́yìn tí o lò ó lára.


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.