Àwọn ohun tí ó lè mú kí èèyàn má lè lo òògùn náà.

Kí ló lè ṣẹlẹ̀ tí mi ò fi gbọ́dọ̀ lo òògùn ìṣẹ́yún nílé?

Má ṣe lo òògùn ìṣẹ́yún ní ilé tí oyún rẹ bá ti ju ọsẹ̀ mọ́kànlá lọ; tí mifepristone tàbí misoprostol bá jẹ́ èèwọ̀ ara rẹ; tí ìlera rẹ ò bá péye tó, tí o bá ní ìṣòro ẹ̀jẹ̀ dídì; tí o bá rò tàbi mọ̀ pé inú ilé ọmọ rẹ kọ́ ni oyún náà wà.


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.