Àwọn ìbéèrè mìíràn tí àwọn èèyàn máa ń béèrè

Kí ni ìyàtọ̀ tí ó wà láàrín òògùn oyún ṣíṣẹ́ àti òògùn àárọ̀ ọjọ́ kejì (ìdènà oyún pàjáwìrì)?

Òògùn idea oyún pàjáwìrì jẹ́ òògùn tí ó múnádóko tí kò sì béwu dé tí a fi ń dènà oyún nígbà tí a bá ní àjọṣepọ̀ láìlo ààbò. Wọ́n máa ń dá iṣẹ́ ẹ̀yà ara ti o máa ń pọ ẹyin dúró tàbí ṣe ìdíwọ́ fún ìpàdé ẹyin àti àtọ̀. Òògùn ìdènà oyún pàjáwìrì ò ní ba oyún tí ó ti dúró jẹ́. Wọ́n sì yàtọ̀ sí àwọn ìlànà oyún ṣíṣẹ́ (tí mifepristone àti misoprostol wà lára rẹ̀). Àwọn ìtọ́jú méjèèjì ṣe pàtàkì sí ìlera ìbí àti ìbálòpọ̀ káàkiri àgbáyé.


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.