Àwọn ìbéèrè mìíràn tí àwọn èèyàn máa ń béèrè

Ṣé oyún ṣíṣẹ́ wà lára àwọn ọ̀nà tí a fi ń dènà oyún?

A ò gbọ́dọ̀ gbé àwọn ọ̀nà tí a lè gbà ṣẹ́yún fún ìlànà ìdènà oyún (ara èyí tí ìdènà oyún pàjáwìrì wà). Àwọn ọ̀nà ìdènà oyún máa ń dí ọ̀nà ẹyin tàbí ṣe ìdíwọ́ fún ìpàdé àtọ̀ àti ẹyin. A ò lè fi àwọn ọ̀nà ìdènà oyún, tí ọkàn lára wọn jẹ́ ìdènà oyún pàjáwìrì ṣẹ́ oyún tí ó ti dúró. Lọ sí www.findmymethod.org láti kọ́ síi nípa àwọn ìlànà ìdènà oyún.


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.