Àwọn ìbéèrè mìíràn tí àwọn èèyàn máa ń béèrè

Ṣé oyún ṣíṣẹ́ ní ìlànà ìṣègùn òyìnbó náàni oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú òògùn? Ṣé oyún ṣíṣẹ́ ní ìlànà ìṣègùn òyìnbó náàni oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú iṣẹ́ abẹ?

Oríṣi ìlànà oyún ṣíṣẹ́ méjì ni ó wà:
1) Oyún ṣíṣẹ́ ní ìlànà ìṣègùn òyìnbó: Nínú ìlànà yìí, a máa ń fi òògùn ṣé oyún. Wọ́n tún máa ń pè é ní "oyún ṣíṣẹ́ láìsí iṣẹ́ abẹ" tàbí "oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú òògùn.
2) Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú iṣẹ́ abẹ: Nínú ìlànà yìí, akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ tí ó dáńtọ́ ni yóò gba ẹnu ọ̀nà ilé ọmọ láti yọ oyún náà nínú ilé ọmọ. Lára àwọn ohun tí wọn máa ń ṣe nínú ìlànà yìí ni, fífà oyún síta (manual vacuum aspiration) àti fífẹ ẹnu ọ̀nà ilé ọmọ láti yọ ohun tí ó wà níbẹ̀ (Dilatation and evacuation).


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.