Oríṣiríṣi àwọn òògùn ìṣẹ́yún
tí ó wà àti lílò wọn

Ṣe mo lè lo misoprostol nílé?

Bẹ́ẹ̀ni, o lè lo misoprostol nílé láìsí ewu. Tí o bá lò ó, gbìyànjú kí o wà níbi tí èrò kò pọ̀ sí (bí ilé rẹ) tí o sì lè fẹ̀gbẹ́ lélẹ̀ fún wákàtí díẹ̀ lẹ́yìn tí o bá lò ó tán. Yóò dára tí ẹnìkan bá wà pẹ̀lú rẹ tí ó lè tọ́jú rẹ, tí ò sì lè po tíì gbígbóná tàbí bá ọ wá nǹkan láti jẹ.


References

This website may require anonymous cookies and various third party services to function properly. You can read our Terms & Conditions and Privacy Policies. By continuing to use this site you are giving us your consent to do this.