Èkó orí èro ayélujára

Courses within safe medical abortion.

Yan èkó tí onífè sí

Àwon èkó tí a sètò fún awon onímò ìlera lóríi bí a ti ń séyún ní ònà tí kòléwu ní ìlànà ìlera. Yan èkó èyí tí ó dára fún o

Èkó orí èro ayélujára

Yan èkó tí onífè sí

Àwon èkó tí a sètò fún awon onímò ìlera lóríi bí a ti ń séyún ní ònà tí kòléwu ní ìlànà ìlera. Yan èkó èyí tí ó dára fún o

Courses within safe medical abortion.

Èkó fún àwon olóógùn

Èkó orí èro ayélujára tí à ń pè ní Medical Abortion (MA) ni a ti sètò fún àwon olóógùn àti àwon tí wón ń sisé ní ilé ògùn láti pèsè ìmò tí yóo mú ìdàgbàsókè dé bá isé won, tí yíó sì mú won yege nínu pípèse ògùn ìséyún ní ìlànà ìlera

Te èkó náàArrowUpRight

Èkó fún àwon akékò ìleraII. Èkó fún àwon akékò ìlera

Èkó orí èro ayélujára tí à ń pè ní Medical Abortion (MA) ni a ti sètò fún àwon akékò ìlera láti pèsè ìmò tó dájú tí yíó mú ìdàgbàsókè dé bá isé won, tí yíó sí múu dájú wípé wón gbaradì láti pèsè ìrànlówó fún àwon obìnrin tí wón ń wá láti séyún tàbí tí wón ti séyún ní ìlànà ìlera.

Te èkó náàArrowUpRight

Òògùn ìséyún ní ìlànà ìlera ní agbègbè àwon tí ó ń ran omoníyàn lówó

Èkó orí èro ayélujára yìí ni a ti sètò láti fi kún ìmò nípa àti bí a se lè ní ètó sí ìséyún ní ìlànà ìlera (tàbí ògùn ìséyún) ní agbègbè àwon tí ó ń ran omoníyàn lówó. Èkó yìí ni a pèsè pèlú àjosepò láàrín ilé isé Medicins Sans Frontieres àti HowToUseAbortionPill.org Nípa ìmò tí íwo yíó kó nínú èkó yìí, wàá lè rii dájú wípé síséyún pèlu ógùn kò panilára, ó wà ní àrówótó, àti wípé ó wà títí. Èkó yìí ni a pèsè pèlú àjosepò láàrín ilé isé Médecins Sans Frontières àti www.HowToUseAbortionPill.org

Te èkó náàArrowUpRight